Font Size
Matiu 2:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 2:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìbẹ̀wò àwọn amòye
2 (A)Lẹ́yìn ìgbà tí a bí Jesu ní Bẹtilẹhẹmu ti Judea, ni àkókò ọba Herodu, àwọn amòye ti ìlà-oòrùn wá sí Jerusalẹmu.
Read full chapter
1 Kronika 24:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kronika 24:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
10 Èkeje sì ni Hakosi,
ẹlẹ́kẹjọ sí ni Abijah,
2 Kronika 31:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 Kronika 31:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìdáwó fún ìjọ́sìn
2 Hesekiah fi lé àwọn àlùfáà àti àwọn ará Lefi lọ́wọ́ sí àwọn ìpín olúkúlùkù wọn gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn gẹ́gẹ́ bí àlùfáà tàbí ará Lefi láti tẹ́ ẹbọ sísun àti ọrẹ ìdàpọ̀, láti ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ láti fi ọpẹ́ fún àti láti kọ àwọn orin ìyìn ní ẹnu-ọ̀nà ibùgbé Olúwa.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.