Add parallel Print Page Options

17 (A)Ohùn kan láti ọ̀run wá sì wí pé, “Èyí sì ni àyànfẹ́ ọmọ mi, ẹni tí inú mi dùn sí gidigidi.”

Read full chapter

18 (A)“Ẹ wo ìránṣẹ́ mi ẹni tí mo yàn.
    Àyànfẹ́ mi ni ẹni tí inú mi dùn sí gidigidi;
èmi yóò fi ẹ̀mí mi fún un.
    Òun yóò sì ṣe ìdájọ́ àwọn kèfèrí.

Read full chapter

Ìránṣẹ́ Olúwa náà

42 (A)“Ìránṣẹ́ mi nìyìí, ẹni tí mo gbéró,
    àyànfẹ́ mi nínú ẹni tí mo láyọ̀;
Èmi yóò fi Ẹ̀mí mi sínú rẹ̀
    òun yóò sì mú ìdájọ́ wá sórí àwọn orílẹ̀-èdè.

Read full chapter

(A)Èmi yóò sì kéde ìpinnu Olúwa:

Ó sọ fún mi pé, “Ìwọ ni ọmọ mi;
    lónìí, èmi ti di baba rẹ.

Read full chapter