Font Size
Matiu 10:26
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 10:26
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
26 (A)(B) “Nítorí náà, ẹ má ṣe bẹ̀rù wọn, nítorí kò sí ohun tó ń bọ̀ tí kò ní í fi ara hàn, tàbí ohun tó wà ní ìkọ̀kọ̀ tí a kò ní mọ̀ ni gbangba.
Read full chapter
Luku 8:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 8:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 (A)Nítorí kò sí ohun tí ó fi ara sin, tí a kì yóò fihàn, tàbí ohun tí a fi pamọ́, ti a kì yóò sì mọ̀ kí ó sì yọ sí gbangba.
Read full chapter
Luku 12:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 12:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 (A)Kò sí ohun tí a bò, tí a kì yóò sì fihàn; tàbí tí ó pamọ́, tí a kì yóò mọ̀.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.