Add parallel Print Page Options

(A)“ ‘Ẹ má ṣe yípadà tọ ère òrìṣà lẹ́yìn, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ rọ ère òrìṣà idẹ fún ara yín. Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.

Read full chapter

“‘Do not turn to idols or make metal gods for yourselves.(A) I am the Lord your God.(B)

Read full chapter

“Ìwọ fẹ́ dájọ́ wọn bí? Ìwọ fẹ́ dájọ́ wọn bí ọmọ ènìyàn? Nítorí náà fi gbogbo ìwà ìríra baba wọn kò wọ́n lójú,

Read full chapter

“Will you judge them? Will you judge them, son of man? Then confront them with the detestable practices of their ancestors(A)

Read full chapter

23 Bẹ́ẹ̀ ni pẹ̀lú ọwọ́ ti mo gbé sókè sí wọn, mo búra fún wọn nínú aginjù pé èmi yóò tú wọn ka sì àárín àwọn orílẹ̀-èdè, èmi yóò sì fọ́n wọn káàkiri ilẹ̀ gbogbo,

Read full chapter

23 Also with uplifted hand I swore to them in the wilderness that I would disperse them among the nations and scatter(A) them through the countries,

Read full chapter

Èèwọ̀ ni ìbọ̀rìṣà jẹ́

15 Ẹ kíyèsára gidigidi, torí pé, ẹ kò rí ìrísí ohunkóhun ní ọjọ́ tí Olúwa bá yín sọ̀rọ̀ ní Horebu láti àárín iná wá. Torí náà ẹ ṣọ́ra yín gidigidi, 16 kí ẹ ma ba à ba ara yín jẹ́ nípa ṣíṣe ère fún ara yín, àní ère lóríṣìíríṣìí yálà èyí tí ó ní ìrísí ọkùnrin tàbí tí obìnrin, 17 tàbí ti ẹranko orí ilẹ̀, tàbí ti ẹyẹ tí ń fò ní òfúrufú, 18 tàbí ti àwòrán onírúurú ẹ̀dá tí ń fà lórí ilẹ̀, tàbí ti ẹja nínú omi.

Read full chapter

Idolatry Forbidden

15 You saw no form(A) of any kind the day the Lord spoke to you at Horeb(B) out of the fire. Therefore watch yourselves very carefully,(C) 16 so that you do not become corrupt(D) and make for yourselves an idol,(E) an image of any shape, whether formed like a man or a woman, 17 or like any animal on earth or any bird that flies in the air,(F) 18 or like any creature that moves along the ground or any fish in the waters below.

Read full chapter

15 (A)“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó fín ère tàbí gbẹ́ òrìṣà ohun tí ó jẹ́ ìríra níwájú Olúwa, iṣẹ́ ọwọ́ oníṣọ̀nà tí ó gbé kalẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀.”

Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Read full chapter

15 “Cursed is anyone who makes an idol(A)—a thing detestable(B) to the Lord, the work of skilled hands—and sets it up in secret.”

Then all the people shall say, “Amen!”(C)

Read full chapter