Add parallel Print Page Options

(A)Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé:

“Ọlọ́run ti fún wọn ní ẹ̀mí oorun,
    àwọn ojú tí kò le ríran
    àti àwọn etí tí kò le gbọ́rọ̀,
títí ó fi di òní olónìí yìí.”

Read full chapter