Add parallel Print Page Options

(A)Ó sì sọ fún Kora àti gbogbo ẹgbẹ́ rẹ̀ pé, “Ní ọ̀la ni Olúwa yóò fi ẹni tí í ṣe tirẹ̀ àti ẹni tó mọ́ hàn, yóò sì mú kí ẹni náà súnmọ́ òun. Ẹni tí ó bá yàn ni yóò mú kí ó súnmọ́ òun.

Read full chapter

13 Olúwa Ọlọ́run wa, àwọn olúwa mìíràn
    lẹ́yìn rẹ ti jẹ ọba lé wa lórí,
    ṣùgbọ́n orúkọ rẹ nìkan ni àwa fi ọ̀wọ̀ fún.

Read full chapter