Font Size
Matiu 9:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 9:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
22 (A)Nígbà tí Jesu sì yí ara rẹ̀ padà tí ó rí i, ó wí pé, “Ọmọbìnrin, tújúká, ìgbàgbọ́ rẹ mú ọ láradà.” A sì mú obìnrin náà láradá ni wákàtí kan náà.
Read full chapter
Marku 5:34
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Marku 5:34
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
34 (A)Jesu sì wí fún un pé, “Ọmọbìnrin, ìgbàgbọ́ rẹ mú ọ láradá: Máa lọ ní àlàáfíà, ìwọ sì ti sàn nínú ààrùn rẹ.”
Read full chapter
Luku 8:48
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 8:48
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
48 (A)Ó sì wí fún un pé, “Ọmọbìnrin, ìgbàgbọ́ rẹ mú ọ láradá; máa lọ ní Àlàáfíà!”
Read full chapter
Luku 18:42
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 18:42
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
42 (A)Jesu sì wí fún un pé, “Ríran; ìgbàgbọ́ rẹ mú ọ láradá.”
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.