Add parallel Print Page Options

Jesu bẹ̀rẹ̀ sí wàásù

12 (A)Nígbà tí Jesu gbọ́ wí pé a ti fi Johanu sínú túbú ó padà sí Galili.

Read full chapter

Pípe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn àkọ́kọ́

14 (A)Lẹ́yìn ìgbà tí ọba Herodu ti fi Johanu sínú ẹ̀wọ̀n tan, Jesu lọ sí Galili, ó ń wàásù ìhìnrere ti ìjọba Ọlọ́run.

Read full chapter

26 Òkìkí èyí sì kàn ká gbogbo ilẹ̀ náà.

Read full chapter

37 (A)Òkìkí rẹ̀ sì kàn níbi gbogbo ní agbègbè ilẹ̀ náà yíká.

Read full chapter