Add parallel Print Page Options

Jesu sọ pé Peteru yóò sẹ́ òun

31 (A)Nígbà náà ni Jesu wí fún wọn pé, “Gbogbo yín ni yóò kọsẹ̀ lára mi ní òru òní. Nítorí a ti kọ ọ́ pé:

“ ‘Èmi yóò kọlu olùṣọ́-àgùntàn
    a ó sì tú agbo àgùntàn náà ká kiri.’

Read full chapter

Jesu sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé Peteru yóò sẹ́ òun

27 (A)Jesu sì wí fún wọn pé, “Gbogbo yín ni ẹ ó sa kúrò lọ́dọ̀ mi, a ti kọ̀wé rẹ pé:

“ ‘Èmi yóò lu olùṣọ́-àgùntàn
    àwọn agbo àgùntàn yóò sì fọ́nká.’

Read full chapter