Add parallel Print Page Options

37 (A)Jesu dáhùn pé, “ ‘Fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ, gbogbo ẹ̀mí rẹ àti gbogbo inú rẹ.

Read full chapter

37 Jesus replied: “‘Love the Lord your God with all your heart and with all your soul and with all your mind.’[a](A)

Read full chapter

Footnotes

  1. Matthew 22:37 Deut. 6:5

29 (A)Jesu dá ọkùnrin yìí lóhùn pé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ nínú àwọn òfin ni èyí tí ó kà báyìí pé: ‘Gbọ́ Israẹli; Olúwa Ọlọ́run wa Olúwa kan ni.

Read full chapter

29 “The most important one,” answered Jesus, “is this: ‘Hear, O Israel: The Lord our God, the Lord is one.[a]

Read full chapter

Footnotes

  1. Mark 12:29 Or The Lord our God is one Lord

30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ, èyí ní òfin kìn-ín-ní.’

Read full chapter

30 Love the Lord your God with all your heart and with all your soul and with all your mind and with all your strength.’[a](A)

Read full chapter

Footnotes

  1. Mark 12:30 Deut. 6:4,5

27 (A)Ó sì dáhùn wí pé, “ ‘Kí ìwọ fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo agbára rẹ, àti gbogbo inú rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ’; àti, ‘ẹnìkejì rẹ bí ara rẹ.’ ”

Read full chapter

27 He answered, “‘Love the Lord your God with all your heart and with all your soul and with all your strength and with all your mind’[a];(A) and, ‘Love your neighbor as yourself.’[b](B)

Read full chapter

Footnotes

  1. Luke 10:27 Deut. 6:5
  2. Luke 10:27 Lev. 19:18