Add parallel Print Page Options

18 (A)“A gbọ́ ohùn kan ní Rama,
    ohùn réré ẹkún àti ọ̀fọ̀ ńlá,
Rakeli ń sọkún àwọn ọmọ rẹ̀.
    Ó kọ̀ láti gbìpẹ̀
nítorí àwọn ọmọ rẹ̀ kò sí mọ́.”

Read full chapter