Matiu 16:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
19 Èmi yóò fún ní àwọn kọ́kọ́rọ́ ìjọba Ọ̀run; Ohun tí ìwọ bá dè ní ayé, òun ni a ó dè ní ọ̀run. Ohunkóhun tí ìwọ bá sì tú ní ayé yìí, a ó sì tú ní ọ̀run.”
Read full chapter
Matthew 16:19
New International Version
19 I will give you the keys(A) of the kingdom of heaven; whatever you bind on earth will be[a] bound in heaven, and whatever you loose on earth will be[b] loosed in heaven.”(B)
Footnotes
- Matthew 16:19 Or will have been
- Matthew 16:19 Or will have been
Matiu 18:18
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
18 (A)“Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, Ohunkóhun tí ẹ̀yin bá dè ní ayé, ni a dè ní ọ̀run. Ohunkóhun ti ẹ̀yin bá sì ti tú ni ayé, á ò tú u ní ọ̀run.
Read full chapter
Matthew 18:18
New International Version
18 “Truly I tell you, whatever you bind on earth will be[a] bound in heaven, and whatever you loose on earth will be[b] loosed in heaven.(A)
Footnotes
- Matthew 18:18 Or will have been
- Matthew 18:18 Or will have been
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.