Luku 8:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
24 (A)Wọ́n sì tọ̀ ọ́ wá wọ́n sì jí i, wí pé, “Olùkọ́, Olùkọ́, àwa yóò ṣègbé!”
Nígbà náà ni ó dìde, ó sì bá ìjì líle àti ríru omi wí; wọ́n sì dúró, ìdákẹ́rọ́rọ́ sì dé.
Read full chapter
Luke 8:24
New International Version
24 The disciples went and woke him, saying, “Master, Master,(A) we’re going to drown!”
He got up and rebuked(B) the wind and the raging waters; the storm subsided, and all was calm.(C)
Luku 8:45
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
45 (A)Jesu sì wí pé, “Ta ni ó fi ọwọ́ kàn mí?”
Nígbà tí gbogbo wọn sẹ́ Peteru àti àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ sọ pé, “Olùkọ́, àwọn ènìyàn ko ní ààyè, wọ́n sì ń kọlù ọ́, ìwọ sì wí pé, Ta ni ó fi ọwọ́ kàn mi?”
Read full chapter
Luke 8:45
New International Version
45 “Who touched me?” Jesus asked.
When they all denied it, Peter said, “Master,(A) the people are crowding and pressing against you.”
Luku 9:33
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
33 (A)Ó sì ṣe, nígbà tí wọ́n lọ kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, Peteru wí fún Jesu pé, “Olùkọ́, ó dára fún wa kí a máa gbé ìhín yìí: jẹ́ kí àwa pa àgọ́ mẹ́ta; ọ̀kan fún ìwọ, àti ọ̀kan fún Mose, àti ọ̀kan fún Elijah.” (Kò mọ èyí tí òun ń wí.)
Read full chapter
Luke 9:33
New International Version
33 As the men were leaving Jesus, Peter said to him, “Master,(A) it is good for us to be here. Let us put up three shelters—one for you, one for Moses and one for Elijah.” (He did not know what he was saying.)
Luku 9:49
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
49 (A)(B) Johanu sì dáhùn ó sì wí fún un pé, “Olùkọ́, àwa rí ẹnìkan ó ń fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde; àwa sì dá a lẹ́kun, nítorí tí kò bá wa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.”
Read full chapter
Luke 9:49
New International Version
49 “Master,”(A) said John, “we saw someone driving out demons in your name and we tried to stop him, because he is not one of us.”
Luku 17:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
13 (A)Wọ́n sì kígbe sókè, wí pé, “Jesu, Olùkọ́, ṣàánú fún wa.”
Read full chapter
Luke 17:13
New International Version
13 and called out in a loud voice, “Jesus, Master,(A) have pity on us!”
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.