Add parallel Print Page Options

39 (A)Nígbà tí Farisi tí ó pè é sì rí i, ó wí nínú ara rẹ̀ pé, “Ọkùnrin yìí ìbá ṣe wòlíì, ìbá mọ ẹni àti irú ẹni tí obìnrin yìí jẹ́ tí ń fi ọwọ́ kàn an, nítorí ẹlẹ́ṣẹ̀ ni.”

Read full chapter

39 When the Pharisee who had invited him saw this, he said to himself, “If this man were a prophet,(A) he would know who is touching him and what kind of woman she is—that she is a sinner.”

Read full chapter

19 (A)Ó sì bi wọ́n pé, “Kín ni?”

Wọ́n sì wí fún un pé, “Ní ti Jesu ti Nasareti, ẹni tí ó jẹ́ wòlíì, tí ó pọ̀ ní ìṣe àti ní ọrọ̀ níwájú Ọlọ́run àti gbogbo ènìyàn,

Read full chapter

19 “What things?” he asked.

“About Jesus of Nazareth,”(A) they replied. “He was a prophet,(B) powerful in word and deed before God and all the people.

Read full chapter

11 (A)Ọ̀pọ̀ ènìyàn sì dáhùn pé, “Èyí ni Jesu, wòlíì náà láti Nasareti ti Galili.”

Read full chapter

11 The crowds answered, “This is Jesus, the prophet(A) from Nazareth in Galilee.”

Read full chapter

14 (A)Nítorí náà nígbà tí àwọn ọkùnrin náà rí iṣẹ́ ààmì tí Jesu ṣe, wọ́n wí pé, “Lóòótọ́ èyí ni wòlíì náà tí ń bọ̀ wá sí ayé.”

Read full chapter

14 After the people saw the sign(A) Jesus performed, they began to say, “Surely this is the Prophet who is to come into the world.”(B)

Read full chapter