Add parallel Print Page Options

(A)Nígbà tí Herodu, sì rí Jesu, ó yọ̀ gidigidi; nítorí tí ó ti ń fẹ́ rí i pẹ́ ó sá à ti ń gbọ́ ìròyìn púpọ̀ nítorí rẹ̀; ó sì ń retí láti rí i kí iṣẹ́ ààmì díẹ̀ ti ọwọ́ rẹ̀ ṣe.

Read full chapter

When Herod saw Jesus, he was greatly pleased, because for a long time he had been wanting to see him.(A) From what he had heard about him, he hoped to see him perform a sign of some sort.

Read full chapter