Lefitiku 19:3
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
3 (A)“ ‘Ẹnìkọ̀ọ̀kan yín gbọdọ̀ bọ̀wọ̀ fún ìyá àti baba rẹ̀, kí ẹ sì ya ọjọ́ ìsinmi mi sí mímọ́. Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.
Read full chapter
Leviticus 19:3
New International Version
3 “‘Each of you must respect your mother and father,(A) and you must observe my Sabbaths.(B) I am the Lord your God.(C)
Deuteronomi 5:16
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
16 (A)(B) Bọ̀wọ̀ fún baba òun ìyá rẹ, bí Olúwa Ọlọ́run yín ti pàṣẹ fún ọ, kí ọjọ́ rẹ kí ó lè pẹ́, àti kí ó lè dára fún ọ ní ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fi fún ọ.
Deuteronomy 5:16
New International Version
Matiu 15:4
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
4 Nítorí Ọlọ́run wí pé, ‘Bọ̀wọ̀ fún Baba òun ìyá rẹ,’ àti pé, ‘Ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ ọ̀rọ̀-òdì sí baba tàbí ìyá rẹ̀, ní láti kú.’
Read full chapter
Matthew 15:4
New International Version
4 For God said, ‘Honor your father and mother’[a](A) and ‘Anyone who curses their father or mother is to be put to death.’[b](B)
Footnotes
- Matthew 15:4 Exodus 20:12; Deut. 5:16
- Matthew 15:4 Exodus 21:17; Lev. 20:9
Marku 7:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
10 (A)Mose fún un yín ní òfin yìí láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run pé, ‘Bọ̀wọ̀ fún baba òun ìyá rẹ.’ Ó tún sọ pé, ‘Ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ̀rọ̀ aburú sí baba tàbí ìyá rẹ̀ ní láti kú ni.’
Read full chapter
Efesu 6:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 (A)“Bọ̀wọ̀ fún baba àti ìyá rẹ,” èyí tí í ṣe òfin kìn-ín-ní pẹ̀lú ìlérí,
Read full chapter
Ephesians 6:2
New International Version
2 “Honor your father and mother”—which is the first commandment with a promise—
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.