Add parallel Print Page Options

12 Epafira, ẹni tí ń ṣe ọ̀kan nínú yín àti ìránṣẹ́ Kristi Jesu kí i yín. Òun fi ìwàyáàjà gbàdúrà nígbà gbogbo fún un yín, kí ẹ̀yin kí ó lè dúró ní pípé nínú ohun gbogbo nínú ìfẹ́ Ọlọ́run.

Read full chapter

23 Epafira, òǹdè ẹlẹgbẹ́ mi nínú Kristi Jesu kí ọ.

Read full chapter