Font Size
Johanu 8:15
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 8:15
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
15 (A)Ẹ̀yin ń ṣe ìdájọ́ nípa ti ara; èmi kò ṣe ìdájọ́ ẹnikẹ́ni.
Read full chapter
Johanu 12:47
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 12:47
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
47 (A)“Bí ẹnikẹ́ni bá sì gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, tí kò sì pa wọ́n mọ́, èmi kì yóò ṣe ìdájọ́ rẹ̀ nítorí tí èmi kò wá láti ṣe ìdájọ́ ayé, bí kò ṣe láti gba ayé là.
Read full chapter
Luku 19:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 19:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
10 Nítorí Ọmọ Ènìyàn dé láti wá àwọn tí ó nù kiri, àti láti gbà wọ́n là.”
Read full chapter
1 Johanu 4:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Johanu 4:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
14 (A)Àwa tí rí, a sì jẹ́rìí pé Baba rán Ọmọ rẹ̀ láti jẹ́ Olùgbàlà fún aráyé.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.