Johanu 5:45-47
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
45 (A)“Ẹ má ṣe rò pé, èmi ó fi yín sùn lọ́dọ̀ Baba: ẹni tí ń fi yín sùn wà, àní Mose, ẹni tí ẹ̀yin gbẹ́kẹ̀lé. 46 Nítorí pé ẹ̀yin ìbá gba Mose gbọ́, ẹ̀yin ìbá gbà mí gbọ́: nítorí ó kọ ìwé nípa tèmi. 47 (B)Ṣùgbọ́n bí ẹ̀yin kò bá gba ìwé rẹ̀ gbọ́, ẹ̀yin ó ti ṣe gbà ọ̀rọ̀ mi gbọ́?”
Read full chapter
John 5:45-47
New International Version
45 “But do not think I will accuse you before the Father. Your accuser is Moses,(A) on whom your hopes are set.(B) 46 If you believed Moses, you would believe me, for he wrote about me.(C) 47 But since you do not believe what he wrote, how are you going to believe what I say?”(D)
Ìṣe àwọn Aposteli 15:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
21 Nítorí òfin Mose nígbà àtijọ́ ṣá ní a ti ń wàásù rẹ̀, ni ìlú gbogbo, a máa ń kà á nínú Sinagọgu ni ọjọọjọ́ ìsinmi.”
Read full chapter
Acts 15:21
New International Version
21 For the law of Moses has been preached in every city from the earliest times and is read in the synagogues on every Sabbath.”(A)
Luku 4:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 A sì fi ìwé wòlíì Isaiah fún un. Nígbà tí ó sì ṣí ìwé náà, ó rí ibi tí a gbé kọ ọ́ pé:
Read full chapter
Luke 4:17
New International Version
17 and the scroll of the prophet Isaiah was handed to him. Unrolling it, he found the place where it is written:
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.