Add parallel Print Page Options

Jesu ṣe ìlérí Ẹ̀mí Mímọ́

15 (A)“Bí ẹ̀yin bá fẹ́ràn mi, ẹ ó pa òfin mi mọ́.

Read full chapter

(A)Ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó bá ń pa òfin rẹ̀ mọ́, lára rẹ̀ ni a gbé mú ìfẹ́ Ọlọ́run pé nítòótọ́. Nípa èyí ni àwa mọ̀ pé àwa ń wà nínú rẹ̀.

Read full chapter

(A)Èyí sì ni ìfẹ́, pé, kí àwa máa rin nípa òfin rẹ̀, èyí ni òfin náà, àní bí ẹ ti gbọ́ ni àtètèkọ́ṣe, pé, kí ẹ̀yin rìn nínú rẹ̀.

Read full chapter