Add parallel Print Page Options

Lára ìpín wọn ní:

Beerṣeba (tàbí Ṣeba), Molada, Hasari-Ṣuali, Bala, Esemu, Eltoladi, Betuli, Horma, Siklagi, Beti-Markaboti, Hasari Susa, Beti-Lebaoti àti Ṣarueli, ìlú wọn jẹ́ mẹ́tàlá àti ìletò wọn.

Aini, Rimoni, Eteri àti Aṣani: Ìlú wọn jẹ́ mẹ́rin àti ìletò wọn: Àti gbogbo àwọn agbègbè ìlú wọ̀nyí títí dé Baalati-Beeri (Rama ní gúúsù).

Èyí ni ilẹ̀ ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ Simeoni, agbo ilé, ní agbo ilé.

Read full chapter