Add parallel Print Page Options

(A)Ife wúrà ni Babeli ní ọwọ́ Olúwa;
    ó sọ gbogbo ayé di ọ̀mùtí.
Gbogbo orílẹ̀-èdè mu ọtí rẹ̀,
    wọ́n sì ti ya òmùgọ̀ kalẹ̀.

Read full chapter

24 (A)Nígbà náà ni Olúwa rọ̀jò iná àti Sulfuru (òkúta iná) sórí Sodomu àti Gomorra—láti ọ̀run lọ́dọ̀ Olúwa wá.

Read full chapter