Add parallel Print Page Options

19 (A)ní dídá ìyìn sí ètè àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀ ní Israẹli.
    Àlàáfíà, àlàáfíà fún àwọn tí ó wà lókèèrè àti nítòsí,”
    ni Olúwa wí, “Àti pé Èmi yóò wo wọ́n sàn.”

Read full chapter

32 (A)Yóò sí ṣe, ẹnikẹ́ni tí ó ba ké pè
    orúkọ Olúwa ní a ó gbàlà:
nítorí ní òkè Sioni àti ní Jerusalẹmu
    ní ìgbàlà yóò gbé wà,
    Olúwa ti wí,
àti nínú àwọn
    ìyókù tí Olúwa yóò pè.

Read full chapter