Add parallel Print Page Options

11 Àwọn ọmọkùnrin Lefi:

Gerṣoni, Kohati àti Merari.

Read full chapter

16 (A)Ìwọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn:

Gerṣoni, Kohati àti Merari.

Lefi lo ẹ̀tàndínlógóje (137) ọdún láyé.

17 Àwọn ọmọ Gerṣoni ni ìran wọn ni:

Libni àti Ṣimei.

18 Àwọn ọmọ Kohati ni:

Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.

Kohati lo ẹ̀tàléláádóje (133) ọdún láyé.

19 Àwọn ọmọ Merari ni:

Mahili àti Muṣi.

Ìwọ̀nyí ni ìran Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn.

20 (B)Amramu sì fẹ́ Jokebedi arábìnrin baba rẹ̀ ní ìyàwó. Jokebedi sì bí Aaroni àti Mose fún un.

Amramu lo ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún láyé.

Read full chapter

(A)Orúkọ àwọn ọmọ Aaroni nìwọ̀nyí, Nadabu ni àkọ́bí, Abihu, Eleasari àti Itamari.

Read full chapter