Eksodu 23:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
6 “Ìwọ kò gbọdọ̀ du aláìní ní ìdájọ́ òdodo.
Read full chapter
Exodus 23:6
New International Version
6 “Do not deny justice(A) to your poor people in their lawsuits.
Deuteronomi 1:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 Ẹ má sì ṣe ojúsàájú ní ìdájọ́: Ẹ ṣe ìdájọ́ ẹni ńlá àti kékeré bákan náà. Ẹ má ṣe bẹ̀rù ẹnikẹ́ni torí pé ti Ọlọ́run ni ìdájọ́. Ẹjọ́ tí ó bá le jù fún un yín ni kí ẹ mú wá fún mi. Èmi yóò sì gbọ́ ọ.
Read full chapter
Deuteronomy 1:17
New International Version
17 Do not show partiality(A) in judging; hear both small and great alike. Do not be afraid of anyone,(B) for judgment belongs to God. Bring me any case too hard for you, and I will hear it.”(C)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.