Add parallel Print Page Options

13 (A)(B) Ìwọ kò gbọdọ̀ pànìyàn.

Read full chapter

17 (A)(B) Ìwọ kò gbọdọ̀ pànìyàn.

Read full chapter

Àwọn adájọ́

18 Ẹ yan àwọn adájọ́ àti àwọn olóyè fún ẹ̀yà a yín kọ̀ọ̀kan, ní gbogbo ìlú tí Olúwa Ọlọ́run yín yóò fún un yín, wọ́n sì gbọdọ̀ máa fi òtítọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn.

Read full chapter