Add parallel Print Page Options

11 Nítorí ní ọjọ́ mẹ́fà ni Olúwa dá ọ̀run àti ayé, òkun àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú wọn, ó sì sinmi ní ọjọ́ keje: nítorí náà ni Olúwa ṣe bùkún ọjọ́ ìsinmi tí ó sì yà á sí mímọ́.

Read full chapter

11 For in six days the Lord made the heavens and the earth,(A) the sea, and all that is in them, but he rested(B) on the seventh day.(C) Therefore the Lord blessed the Sabbath day and made it holy.

Read full chapter

Ẹni tí ó dá ọ̀run àti ayé,
    òkun àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú wọn,
    ẹni tí ó pa òtítọ́ mọ́ títí ayé.

Read full chapter

He is the Maker of heaven(A) and earth,
    the sea, and everything in them—
    he remains faithful(B) forever.

Read full chapter