Add parallel Print Page Options

Ìdájọ́ níwájú ẹni ìgbàanì

(A)“Bí mo ṣe ń wò,

“a gbé ìtẹ́ ọba kan kalẹ̀,
    ẹni ìgbàanì jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀,
Aṣọ rẹ̀ funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú;
    irun orí rẹ̀ funfun bí òwú,
ìtẹ́ ọba rẹ̀ rí bí ọwọ́ iná.
    Àwọn kẹ̀kẹ́ rẹ ń jó bí i iná.

Read full chapter

“As I looked,

“thrones were set in place,
    and the Ancient of Days(A) took his seat.(B)
His clothing was as white as snow;(C)
    the hair of his head was white like wool.(D)
His throne was flaming with fire,
    and its wheels(E) were all ablaze.

Read full chapter

22 títí ẹni ìgbàanì fi dé, ó sì ṣe ìdájọ́ ìdáláre fún àwọn ẹni mímọ́ Ọ̀gá-ògo, àsìkò náà sì dé nígbà tí àwọn ẹni mímọ́ náà jogún ìjọba.

Read full chapter

22 until the Ancient of Days came and pronounced judgment in favor of the holy people of the Most High, and the time came when they possessed the kingdom.(A)

Read full chapter

27 Nígbà náà, ni a ó gba ìjọba, agbára àti títóbi ìjọba rẹ̀ ní abẹ́ gbogbo ọ̀run, a ó sì fi fún àwọn ẹni mímọ́, àwọn ènìyàn Ọ̀gá-ògo. Ìjọba rẹ̀ yóò jẹ́ ìjọba títí ayé, gbogbo aláṣẹ ni yóò máa ṣe ìgbọ́ràn sí i, wọn yóò sì máa sìn ín.’

Read full chapter

27 Then the sovereignty, power and greatness of all the kingdoms(A) under heaven will be handed over to the holy people(B) of the Most High.(C) His kingdom will be an everlasting(D) kingdom, and all rulers will worship(E) and obey him.’

Read full chapter