Add parallel Print Page Options

Má ṣe gbé ara rẹ ga níwájú ọba,
    má sì ṣe jìjàdù ààyè láàrín àwọn ènìyàn pàtàkì
Ó sàn kí ó wí fún ọ pé, “Gòkè wá síhìn-ín”
    ju wí pé kí ó dójútì ọ́ níwájú ènìyàn pàtàkì.

Read full chapter

43 (A)“Ègbé ni fún yín, ẹ̀yin Farisi, àgàbàgebè! Nítorí tí ẹ̀yin fẹ́ ipò ọlá nínú Sinagọgu, àti ìkíni ní ọjà.

Read full chapter

46 “Ẹ máa kíyèsára lọ́dọ̀ àwọn akọ̀wé, tí wọ́n fẹ́ láti máa rìn nínú aṣọ gígùn, tí wọ́n sì fẹ́ ìkíni ní ọjà, àti ibùjókòó ọlá nínú Sinagọgu, àti ipò ọlá ní ibi àsè;

Read full chapter