Add parallel Print Page Options

13 (A)àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run sì ṣubú sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí igi ọ̀pọ̀tọ́ tí ń rẹ̀ àìgbó èso rẹ̀ dànù, nígbà tí ẹ̀fúùfù ńlá bá mì í. 14 A sì ká ọ̀run kúrò bí ìwé tí a ká, àti olúkúlùkù òkè àti erékùṣù ní a sì ṣí kúrò ní ipò wọn.

Read full chapter

13 and the stars in the sky fell to earth,(A) as figs drop from a fig tree(B) when shaken by a strong wind. 14 The heavens receded like a scroll being rolled up,(C) and every mountain and island was removed from its place.(D)

Read full chapter