Add parallel Print Page Options

29 Gbogbo ìlú náà sì kún fún ìrúkèrúdò: wọ́n sì fi ọkàn kan rọ́ wọn sí inú ilé ìṣeré, wọ́n sì mú Gaiu àti Aristarku ara Makedonia, àwọn ẹlẹgbẹ́ Paulu nínú ìrìnàjò.

Read full chapter

29 Soon the whole city was in an uproar. The people seized Gaius(A) and Aristarchus,(B) Paul’s traveling companions from Macedonia,(C) and all of them rushed into the theater together.

Read full chapter

(A)Alàgbà,

Sì àyànfẹ́ obìnrin ọlọ́lá àti àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn tí mo fẹ́ ní òtítọ́, kì í sì í ṣe èmi nìkan, ṣùgbọ́n gbogbo àwọn tí ó mọ òtítọ́ pẹ̀lú;

Read full chapter

The elder,(A)

To the lady chosen by God(B) and to her children, whom I love in the truth(C)—and not I only, but also all who know the truth(D)

Read full chapter