Add parallel Print Page Options

21 Ǹjẹ́ bí nǹkan wọ̀nyí tí parí tan, Paulu pinnu nínú ọkàn rẹ̀ pé, nígbà tí òun bá kọjá ní Makedonia àti Akaia, òun ó lọ sí Jerusalẹmu, ó wí pé, “Lẹ́yìn ìgbà tí mo bá dé ibẹ̀, èmi kò lè ṣàìmá dé Romu pẹ̀lú.”

Read full chapter

21 After all this had happened, Paul decided[a] to go to Jerusalem,(A) passing through Macedonia(B) and Achaia.(C) “After I have been there,” he said, “I must visit Rome also.”(D)

Read full chapter

Footnotes

  1. Acts 19:21 Or decided in the Spirit

10 (A)nínú àdúrà mi ìgbà gbogbo; mo tún ń gbàdúrà wí pé nípa oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run kí ọ̀nà ó ṣí fún mi láti wá sọ́dọ̀ yín.

11 Nítorí èmi ń fẹ́ gidigidi láti tọ̀ yín wá, kí èmi lè fún yín ní ẹ̀bùn ẹ̀mí díẹ̀, kí a bá a le sọ yín di alágbára nínú Olúwa,

Read full chapter

10 in my prayers at all times;(A) and I pray that now at last by God’s will(B) the way may be opened for me to come to you.(C)

11 I long to see you(D) so that I may impart to you some spiritual gift(E) to make you strong—

Read full chapter

32 (A)kí èmi le fi ayọ̀ tọ̀ yín wa, nípa ìfẹ́ Ọlọ́run, àti kí èmi lè ní ìtura pọ̀ pẹ̀lú yín.

Read full chapter

32 so that I may come to you(A) with joy, by God’s will,(B) and in your company be refreshed.(C)

Read full chapter